Audio: Infinity – Aye Ole

 Infinity - Aye Ole

Aye Ole

Infinity
Infinity – Aye Ole Posted in: Naija Gospel Song. Song is available for download in MP3 format. Download Audio Infinity – Aye Ole.

Lyrics

Omo eniyan f’eti si
oro agba, bi o she l’owuro
A she lowo ale

Verse 1
Bowun ko pe titi, iya aye wa o n bo wa d’opin
Aimola eda lo mu eda saniyan ra
Olorun ti seleri, oro baba ko ni ye
Aini gbaggbao lo mu eda raropin
Bi okun n fo, Ti osa n sa, otito wa laaye
Igbabo ni orisun ohun gbogbo

[Chorus]
Ouh, Aye yi ko male
Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole [x4 ]

Verse 2
Oni suuru, ape koto je, koni jebaje
Ai mani suuru lo n mu are eni bo wa debi
F’oju re womi ore k’Oluwa le foju re wo
Abiku ti d’abiye ninu aye mi
[Repeat]

[Chorus]

Bridge
Aye re ko ma ni le
Aye to ba ba Olorun rin, o sho ri re
[Repeat]

Bowun ko pe titi, iya aye wa o n bo wa d’opinSource: BusysingingDownload Audio Infinity – Aye Ole

Your Reaction?
  • Gbam (2)
  • LWKMD (2)
  • Eh-Yah (0)
  • Chai! (0)
  • Haba (0)
×
Latest Nigerian Music
Browse & Search
Free – Google Play
Install

Loading Facebook Comments ...